9ice – Iwaju Lyrics

9ice Iwaju D'Tunes

9ice – Iwaju Lyrics

Read ‘Iwaju Lyrics’ by 9ice below;
DOWNLOAD AUDIO HERE

It’s Dtunes again
Huhhh
Huuuu
Huhuhuh ehh
Uhum see

Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
want song, wants favour
E maa ríran wò ti n ba k’orin
>mo rí èèmọ l’agege, ajá w’ewu o roṣọ
Iwájú iwájú

iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo

ẹnu ẹni laa fi kọ meejẹ̀
ẹnu ẹni ní power
give me more power, more, more blessings

Ti n ba kankun wàá fí fún mi
ìbéèrè mí re o, jẹ o leesi
Give me more power, more, more blessings

many wey you don bless, I follow them celebrate
>many wey you give power, ???????

Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
>Iwájú iwájú laa máa máa lo

>Aro wa ti weere l’aiye
iwaju ni n máa má lo

Lókè, lókè looke ni n máa má lọ

b’ọta mi p’ogun, p’ogbon won lee lasan
iwájú ní n máa má lo

lókè, lókè looke ni n máa má lọ

Iná tí ọmọ oko ya, l’ọmo alè fí sun iṣu je

lókè, lókè looke ni n máa má lọ

Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Want song, wants favour
e maa ríran wò ti n ba k’orin
>mo rí èèmọ l’agege, ajá w’ewu o roṣọ

Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo

Leave a comment