[Lyrics] Slimcase ft. Zlatan – Pongilah

by Staff

Slimcase Zlatan Pongilah

Pongilah lyrics by Slimcase & Zlatan

Read Slimcase ft Zlatan Ibile ‘Pongilah’ full lyrics below; STREAM/DOWNLOAD MP3

Intro;

(?)
Fresh
Astalivi give dem

Verse 1 – Slimcase

Okay, o ti ko si owo aye, o ti wo’nu IG, o’n ti wa content, o’n ti wa repost

O tin gbondi gbuse, igbese

Chorus

Awon isin pongilah kan le la, awon isin pongilah pongilah, awon isin kan le la, awon isin pongilah pongilah pongilah

Awon isin pongilah kan le la, awon isin pongilah pongilah, awon isin kan le la, awon isin pongilah pongilah ponwon la

Verse 2 – Slimcase

Otunba lamba, won l’oti tun mugbe le, o’n ti’n ta won, ta won bi won shey won shey da’ko ni

Enu e shey wa n yo, s’olo ijabe ni, ara to ma san pawon n fagbo lowo oh

Fagbo ti e ni kin fa temi, k’eruku igbo kan ma lo Di’kan lo’wo oh

(?), coaste, coaste, coaste, coaste

Omi oyan lo’dun ju, ewa wo sokokto to ga ju,
Omi oyan lo’dun ju, ewa wo sokokto to ga ju

Chorus

Awon isin pongilah kan le la, awon isin pongilah pongilah, awon isin kan le la, awon isin pongilah pongilah pongilah

Awon isin pongilah kan le la, awon isin pongilah pongilah, awon isin kan le la, awon isin pongilah pongilah ponwon la

Verse 2 – Zlatan Ibile

Shebi Oloun lo da obo
Eniyan lo de da dido, wa fe lo fun e iwo ni wa jawon pe iwo ko ni ibo

Di e omo okunrin se ko to, kini yen se o ni dildo, o ni la ti kan left and right, k’an mo pe iwo gan set arrow

Igboro ni mi omo Havana (?)

Mi need la ti je (?), ki e to mo pe omo igboro ni mi pe mo clever

Omo ogbon,omo ogbon, eja to wa ninu odo e le je tan

Ah Astalivi give dem

Outro

(?)
Slimcase Zlatan
It’s STG

Check Also

Leave a comment